| ||
Script: Awọ ara ọmọ inu oyun naa ni asiko yi yio mọ gaara nitori pe ko nipọn pupọ. Bi awọ ara naa se nnipọn sii, ni mimọ ti o mọ yio maa dinku, eyiti o tumọ si wipe a le maa wo bi awọn ẹya inu ara ti ndagba, fun osu kan sii. | ||
All ages referenced to fertilization, not last menstrual period. |