| ||
Script: Bakanna, ni ọsẹ karun, atẹlẹwọ ọmọ inu oyun naa yio bẹrẹ sii farahan, kerekere yio si bẹrẹ si ni farahan lati ọS̩u karun ati aabọ. Ni bayi, a o S̩akiyesi atẹlẹwọ ti ọwọ osi ati ti ọrun ọwọ, ni ọsẹ karun ati ọjọ mẹfa. | ||
All ages referenced to fertilization, not last menstrual period. |