| ||
|
Script: tabi mita kan. Bi a ba le tu gbogbo DNA yi palẹ ninu ọkẹ aimọye ẹyin keekeke ti o wa ni ara agbalagba enia, yio gun to iwọn mẹtalelọgọta biliọnu maili. Gigun rẹ yi to ki a rin irin ajo lati aye lọ si ibiti oorun wa, ati ki a pada ni ọọdun igba, o le ni ogoji. | ||
| All ages referenced to fertilization, not last menstrual period. |