Skip Navigation
The Endowment for Human Development
The Endowment for Human Development
Improving lifelong health one pregnancy at a time.
Donate Now Get Free Videos

Movie Theater

The Morula and Blastocyst


5 days

From The Biology of Prenatal Development.Buy Now

Script: Laarin ọjọ mẹta si mẹrin lẹhin idapọ ẹyin ọkunrin ati obirin, ẹyin naa yio maa pin si ọna pupọ, wọn a ri rogodo, a si npe oyun inu naa nisisiyi ni morula.

Laarin ọjọ mẹrin si marun, iho kan yio waye laarin awọn ẹyin rogodo wọnyi, a si npe oyun inu naa nisisiyi ni bilasitosisiti.

Awọn ẹyin keekeke ti o wa ninu bilasitosisiti yi ni a npe ni akojọpọ ẹyin ti inu, eyiti yio ko ara wọn jọ pọ lati di ori, ara, ati awọn ẹya ara miran ti o S̩e pataki fun idagbasoke ọmọ enia.

All ages referenced to fertilization, not last menstrual period.
See Snapshots   |   Log in to create a playlist
Fertilization 2
Fertilization 2
Cell Division
Cell Division
The Morula and Blastocyst
The Morula and Blastocyst
3 Billion Base Pairs per Cell
3 Billion Base Pairs per Cell
Amnion and Germ Layers
Amnion and Germ Layers
Early Embryonic Development
Early Embryonic Development
When does health begin? Find out now.
Tell your story. Create your own pregnancy calendar.