Script: ỌSẸ MẸWA
Orisirisi awọn idagbasoke ti nwaye laarin ọsẹ kẹsan si ikẹwa yio mu ki ara ọmọ naa o tobi sii bi iwọn marundinlọgọrin ninu ọgọrun.