| ||
Script: OS̩U MẸTA Laarin ọsẹ kọkanla si ikejila, iwọn ara ọmọ inu oyun naa yio pọ sii pẹlu iwọn ọgọta ninu ọgọrun. Ọsẹ kejila ni opin ipele akọkọ ninu mẹta, igba ti obirin fi nloyun. | ||
All ages referenced to fertilization, not last menstrual period. One month = 4 weeks. |