| ||
Script: Yatọ si bi o ti ma nS̩e tẹlẹ ri, bi a ba fọwọkan ẹnu ọmọ inu oyun yi, yio yirapada si ọkankan ibiti a ti fọwọkan-an, yio si la ẹnu rẹ. Iru ifesi bayi ni a npe ni “rutini rifulẹkisi” o si ma ntẹsiwaju lẹhin ti ọmọ naa ba d’aye tan, ninu eyiti i ma ran ọmọ lọwọ lati wa ibiti ori-ọmu iya rẹ wa, nigbati o ba fẹ mu ọmu. | ||
All ages referenced to fertilization, not last menstrual period. One month = 4 weeks. |